1
ISIKIẸLI 23:49
Yoruba Bible
N óo da èrè ìṣekúṣe yín le yín lórí, ẹ óo sì jìyà ẹ̀ṣẹ̀ ìbọ̀rìṣà yín. Ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA Ọlọrun.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ISIKIẸLI 23:49
2
ISIKIẸLI 23:35
Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní, “Nítorí pé o ti gbàgbé mi, o sì ti kọ̀ mí sílẹ̀, o óo jìyà ìṣekúṣe ati àgbèrè rẹ.”
Ṣàwárí ISIKIẸLI 23:35
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò