1
ISIKIẸLI 20:20
Yoruba Bible
Ẹ máa pa àwọn ọjọ́ ìsinmi mi mọ́, kí wọ́n lè jẹ́ àmì láàrin èmi pẹlu yín, kí ẹ lè mọ̀ pé èmi OLUWA ni Ọlọrun yín.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ISIKIẸLI 20:20
2
ISIKIẸLI 20:19
Mo ní èmi OLUWA ni Ọlọrun yín. Ẹ máa rìn ní ọ̀nà mi, kí ẹ sì máa pa òfin mi mọ́.
Ṣàwárí ISIKIẸLI 20:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò