1
ẸKISODU 39:43
Yoruba Bible
Mose wo gbogbo iṣẹ́ náà, ó rí i pé wọ́n ṣe é gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ, Mose sì súre fún wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ẸKISODU 39:43
2
ẸKISODU 39:42
Gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose, ni àwọn eniyan Israẹli ṣe gbogbo iṣẹ́ náà.
Ṣàwárí ẸKISODU 39:42
3
ẸKISODU 39:32
Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo iṣẹ́ àgọ́ àjọ náà ṣe parí, àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun gbogbo gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.
Ṣàwárí ẸKISODU 39:32
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò