1
ẸSITA 10:3
Yoruba Bible
Modekai tíí ṣe Juu ni igbákejì sí Ahasu-erusi ọba. Ó tóbi, ó sì níyì pupọ láàrin àwọn Juu, nítorí pé ó ń wá ire àwọn eniyan rẹ̀, ó sì ń sọ̀rọ̀ alaafia fún gbogbo wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ẸSITA 10:3
2
ẸSITA 10:2
Gbogbo iṣẹ́ agbára ati ipá rẹ̀, ati bí ó ṣe gbé Modekai ga sí ipò ọlá, ni a kọ sinu ìwé ìtàn àwọn ọba Media ati ti Pasia.
Ṣàwárí ẸSITA 10:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò