1
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:9
Yoruba Bible
Ìwọ ọdọmọkunrin, máa yọ̀ ní ìgbà èwe rẹ, kí inú rẹ máa dùn; máa ṣe bí ọkàn rẹ ti ń fẹ́, ati bí ó ti tọ́ lójú rẹ. Ṣugbọn ranti pé, Ọlọrun yóo ṣe ìdájọ́ gbogbo ohun tí o bá ṣe.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:9
2
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:10
Gbé ìbànújẹ́ kúrò lọ́kàn rẹ, má sì gba ìrora láàyè lára rẹ, nítorí asán ni ìgbà èwe ati ìgbà ọmọde.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:10
3
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:4
Ẹni tí ń wo ojú afẹ́fẹ́ kò ní fún irúgbìn kankan, ẹni tí ó bá sì ń wo ṣúṣú òjò kò ní kórè.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:4
4
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:5
Gẹ́gẹ́ bí o kò ti mọ bí ẹ̀mí ṣe ń wọ inú ọmọ ninu aboyún, bẹ́ẹ̀ ni o kò mọ̀ bí Ọlọrun ṣe dá ohun gbogbo.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:5
5
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:6
Fún irúgbìn ní àárọ̀, má sì ṣe dáwọ́ dúró ní ìrọ̀lẹ́, nítorí o kò mọ èyí tí yóo dàgbà, bóyá ti òwúrọ̀ ni tabi ti ìrọ̀lẹ́, tabi àwọn mejeeji.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:6
6
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:2
Gbin àwọn kan síhìn-ín, gbin àwọn kan sọ́hùn-ún, gbìn ín káàkiri oko nítorí o kò mọ ohun tí ó lè ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la.
Ṣàwárí ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 11:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò