1
KOLOSE 4:6
Yoruba Bible
Ọ̀rọ̀ ọmọlúwàbí ni kí ó máa ti ẹnu yín jáde nígbà gbogbo, ọ̀rọ̀ tí ó bá etí mu, kí ẹ lè mọ bí ó ti yẹ láti dá ẹnikẹ́ni tí ẹ bá ń bá sọ̀rọ̀ lóhùn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KOLOSE 4:6
2
KOLOSE 4:2
Ẹ tẹra mọ́ adura gbígbà. Ẹ máa fi ọkàn bá adura yín lọ. Kí ẹ sì máa dúpẹ́.
Ṣàwárí KOLOSE 4:2
3
KOLOSE 4:5
Ẹ máa gbé ìgbé-ayé yín pẹlu ọgbọ́n níwájú àwọn alaigbagbọ. Ẹ má ṣe jẹ́ kí àkókò kan kọjá láìjẹ́ pé ẹ lò ó bí ó ti yẹ.
Ṣàwárí KOLOSE 4:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò