1
JOHANU KẸTA 1:2
Yoruba Bible
Olùfẹ́, mo gbadura pé kí ó dára fún ọ ní gbogbo ọ̀nà ati pé kí o ní ìlera, gẹ́gẹ́ bí o ti ní ìlera ninu ẹ̀mí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí JOHANU KẸTA 1:2
2
JOHANU KẸTA 1:11
Olùfẹ́, má tẹ̀lé àpẹẹrẹ burúkú, ṣugbọn tẹ̀lé àpẹẹrẹ rere. Ọ̀dọ̀ Ọlọrun ni ẹni tí ó bá ń ṣe rere ti wá. Ẹni tí ó bá ń ṣe burúkú kò mọ Ọlọrun.
Ṣàwárí JOHANU KẸTA 1:11
3
JOHANU KẸTA 1:4
Ayọ̀ mi kì í lópin, nígbà tí mo bá gbọ́ pé àwọn ọmọ mi ń gbé ìgbé-ayé òtítọ́.
Ṣàwárí JOHANU KẸTA 1:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò