1
SAMUẸLI KEJI 22:3
Yoruba Bible
Ọlọrun mi, àpáta mi, ọ̀dọ̀ ẹni tí mo sá pamọ́ sí. Àpáta mi ati ìgbàlà mi, ààbò mi ati ibi ìpamọ́ mi, olùgbàlà mi, ìwọ ni o gbà mí lọ́wọ́ ìwà ipá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 22:3
2
SAMUẸLI KEJI 22:31
Ní ti Ọlọrun yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀, òtítọ́ ni ìlérí OLUWA, ó sì jẹ́ apata fun gbogbo àwọn tí wọ́n bá sápamọ́ sábẹ́ ààbò rẹ̀.
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 22:31
3
SAMUẸLI KEJI 22:2
“OLUWA ni àpáta mi, ààbò mi, ati olùgbàlà mi
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 22:2
4
SAMUẸLI KEJI 22:33
Ọlọrun yìí ni ààbò mi tí ó lágbára, ó mú gbogbo ewu kúrò ní ọ̀nà mi.
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 22:33
5
SAMUẸLI KEJI 22:29
“OLUWA, ìwọ ni ìmọ́lẹ̀ mi, ìwọ ni o sọ òkùnkùn mi di ìmọ́lẹ̀.
Ṣàwárí SAMUẸLI KEJI 22:29
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò