1
KRONIKA KEJI 7:14
Yoruba Bible
bí àwọn eniyan mi, tí à ń fi orúkọ mi pè, bá rẹ ara wọn sílẹ̀, tí wọ́n bá gbadura, tí wọ́n sì wá ojurere mi, tí wọ́n bá yipada kúrò ní ọ̀nà burúkú wọnyi; n óo gbọ́ láti ọ̀run, n óo dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n, n óo sì wo ilẹ̀ wọn sàn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KRONIKA KEJI 7:14
2
KRONIKA KEJI 7:15
Nisinsinyii, n óo fojú sílẹ̀, etí mi yóo sì ṣí sí adura tí wọ́n bá gbà níbí yìí.
Ṣàwárí KRONIKA KEJI 7:15
3
KRONIKA KEJI 7:16
Mo ti yan ibí yìí, mo sì ti yà á sí mímọ́, kí á lè máa jọ́sìn ní orúkọ mi níbẹ̀ títí lae. Ojú ati ọkàn mi yóo wà níbẹ̀ nígbà gbogbo.
Ṣàwárí KRONIKA KEJI 7:16
4
KRONIKA KEJI 7:13
Nígbà tí mo bá sé ojú ọ̀run, tí òjò kò bá rọ̀, tabi tí mo pàṣẹ fún eṣú láti ba oko jẹ́, tabi tí mo rán àjàkálẹ̀ àrùn sí ààrin àwọn eniyan mi
Ṣàwárí KRONIKA KEJI 7:13
5
KRONIKA KEJI 7:12
Lẹ́yìn náà, OLUWA fara han Solomoni lóru, ó ní, “Mo ti gbọ́ adura rẹ, mo sì ti yan ibí yìí ní ilé ìrúbọ fúnra mi.
Ṣàwárí KRONIKA KEJI 7:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò