1
SAMUẸLI KINNI 12:24
Yoruba Bible
Ẹ máa bẹ̀rù OLUWA, kí ẹ sì máa sìn ín pẹlu gbogbo ọkàn yín. Ẹ ranti àwọn nǹkan ńláńlá tí ó ti ṣe fun yín.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 12:24
2
SAMUẸLI KINNI 12:22
OLUWA kò ní ta eniyan rẹ̀ nù, nítorí orúkọ ńlá rẹ̀, nítorí pé ó wù ú láti ṣe yín ní eniyan rẹ̀.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 12:22
3
SAMUẸLI KINNI 12:20
Samuẹli dá wọn lóhùn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ohun tí ẹ ṣe burú, sibẹsibẹ ẹ má ṣe yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA, ṣugbọn ẹ máa sìn ín pẹlu gbogbo ọkàn yín.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 12:20
4
SAMUẸLI KINNI 12:21
Ẹ má tẹ̀lé àwọn oriṣa; ohun asán tí kò lérè, tí kò sì lè gbani ni wọ́n.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 12:21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò