1
SAMUẸLI KINNI 1:11
Yoruba Bible
Hana bá OLUWA jẹ́jẹ̀ẹ́ ó ní, “OLUWA àwọn ọmọ ogun, bí o bá ṣíjú wo ìyà tí èmi iranṣẹ rẹ ń jẹ, tí o kò gbàgbé mi, tí o fún mi ní ọmọkunrin kan, n óo ya ọmọ náà sọ́tọ̀ fún ìwọ OLUWA ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, abẹ kò sì ní kàn án lórí.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 1:11
2
SAMUẸLI KINNI 1:10
Inú Hana bàjẹ́ gan-an, ó bẹ̀rẹ̀ sí gbadura sí OLUWA, ó sì ń sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 1:10
3
SAMUẸLI KINNI 1:15
Hana dá a lóhùn, pé, “Rárá o, oluwa mi, n kò fẹnu kan ọtí waini tabi ọtí líle. Ìbànújẹ́ ló bá mi, tóbẹ́ẹ̀ tí mo fi ń gbadura, tí mo sì ń tú ọkàn mi jáde fún OLUWA.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 1:15
4
SAMUẸLI KINNI 1:27
Ọmọ yìí ni mò ń tọrọ lọ́wọ́ OLUWA, ó sì fún mi ní ohun tí mo bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀.
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 1:27
5
SAMUẸLI KINNI 1:17
Eli bá dá a lóhùn, ó ní, “Máa lọ ní alaafia, Ọlọrun Israẹli yóo fún ọ ní ohun tí ò ń tọrọ lọ́wọ́ rẹ̀.”
Ṣàwárí SAMUẸLI KINNI 1:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò