1
KỌRINTI KINNI 3:16
Yoruba Bible
Àbí ẹ kó mọ̀ pé Tẹmpili Ọlọrun ni yín ni, ati pé Ẹ̀mí Ọlọrun ń gbé inú yín?
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 3:16
2
KỌRINTI KINNI 3:11
Nítorí kò sí ìpìlẹ̀ kan tí ẹnikẹ́ni tún lè fi lélẹ̀ mọ́, yàtọ̀ sí èyí tí Ọlọrun ti fi lélẹ̀, tíí ṣe Jesu Kristi.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 3:11
3
KỌRINTI KINNI 3:7
Nítorí èyí, kì í ṣe ẹni tí ń gbin nǹkan, tabi ẹni tí ń bomi rin ín ni ó ṣe pataki, bíkòṣe Ọlọrun tí ó ń mú un dàgbà.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 3:7
4
KỌRINTI KINNI 3:9
Nítorí alábàáṣiṣẹ́pọ̀ ni wá lọ́dọ̀ Ọlọrun. Ẹ̀yin ni ọgbà Ọlọrun. Tẹmpili Ọlọrun sì ni yín.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 3:9
5
KỌRINTI KINNI 3:13
iṣẹ́ olukuluku yóo farahàn kedere ní ọjọ́ ìdájọ́, nítorí iná ni yóo fi í hàn. Iná ni a óo fi dán iṣẹ́ olukuluku wò.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 3:13
6
KỌRINTI KINNI 3:8
Ọ̀kan ni ẹni tí ó ń gbin irúgbìn ati ẹni tí ó ń bomi rin ín. Nígbà tí ó bá yá, ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn yóo gba èrè tirẹ̀ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ bá ti rí.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 3:8
7
KỌRINTI KINNI 3:18
Kí ẹnikẹ́ni má ṣe tan ara rẹ̀ jẹ. Bí ẹnìkan ninu yín bá rò pé òun gbọ́n ọgbọ́n ti ayé yìí, kí ó ka ara rẹ̀ sí òmùgọ̀ kí ó lè gbọ́n.
Ṣàwárí KỌRINTI KINNI 3:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò