← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 7

Òrin Dafidi ati Ówè Ni Ojo Mokanlelogbon
Ọjọ́ Mọ́kànlé lọ́gbọ̀n
Iwe Órin Dafidi ati Iwe Òwè kùn fun opolopo Orin, Èwí ati opolopo akosile - ti o nfi ijoosin otito han, ipongbe, ogbon, Ife, ilakaka ati otito. Alakale yii yo mu o ka gbogbo Orin Dafidi ati Ówè Ni Ojo Ookanlelogbon pere. Nihin, Ó sè alabapade Olorun, O si ri itunu, agbara, itoju, ati igbiyanju ti o wa ninu gbogbo iriri eniyan.