← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 37:5
![ỌLỌ́RUN + ÌLÉPA: Ọ̀nà Láti Gbé Ìlépa Kalẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí Kristẹni](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F13611%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
ỌLỌ́RUN + ÌLÉPA: Ọ̀nà Láti Gbé Ìlépa Kalẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí Kristẹni
Ojọ́ Márùn-ún
Ǹjẹ́ o dára láti ní ìlépa gégé bí Kristẹni? Báwo ní o ṣe lẹ̀ mọ̀ tí ìlépa rẹ bá wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tàbí ara rẹ? Àti wípé báwo ni ìlépa Kristẹni ṣe rí ní pàtó? Nínú ètò kíkà ọlọ́jọ́ márùn-ún yìí, o máa ṣàwárí nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láti rí ìtọ́sọ́nà lórí gbígbé ìlépa tó kún fún ore-ọ̀fẹ́ kalẹ̀!