Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 23:4
![Ìdánilójú](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F73%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Ìdánilójú
Ọjọ́ Mẹ́rin
Olórun fé jé kí o mò pé a tí gbà onlà àti pé ìwo yóò lọ sí òrun! Ìdánilójú rè ń dàgbà sí nípasẹ ìbápàdé pẹ̀lú Olórun àti ṣíṣe àsàrò nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ̀. Àwọn ẹsẹ̀ tó tẹ̀lé, nígbà tí o bá há wọn sórí, lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti simi ni ìdánilójú nínú Ọlọ́run ní gbogbo ọjọ́ ayé rè. Jé kí ayé rẹ ní ìyípadà nípa híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí! Fún ìlànà ekún rẹ́rẹ́ fún híhá Àwọn Ìwé Mímó sórí, lọ si MemLok.com
![Fífetí sì Ọlọ́run](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F1763%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Fífetí sì Ọlọ́run
Ọjọ́ méje
Amy Groeschel ti kọ ètò bíbélì yìí ní ìrètí pé yóò di ìtẹ́wọ́gbà bíi wípé ó wá tààrà láti ọkàn Ọlọ́run olùfẹ́ wa sí ọkàn rẹ. Àdúrà Òun tìkálára ni wípé yóò kó̩ ọ láti yàgò fún ohùn tí ń tako ni àti láti tani jí sí ìfiyè sí ohùn rẹ̀.
![Rin Ìrìn-Àjò Rẹ Láì Sí Ẹrú Wúwo](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F13407%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Rin Ìrìn-Àjò Rẹ Láì Sí Ẹrú Wúwo
Ọjọ́ Méje
Ní àkókò pọ̀pọ̀sìnsìn ọ́dún Kérésì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wa ló máa ń fajúro nítorí wàhálà àti àníyàn tó jẹmọ́ ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ẹbí, làálàá ìṣúná, ìpinnu ìdágìrì àti ìjákulẹ̀ nípa àwọn ìrètí wa. Wàyì o, gbé ìgbésẹ. Mí kanlẹ̀. Bẹ̀rẹ̀ ètò Bíbélì Life.Church yí láti ní òye wípé ẹrù náà tó ń rìn wá mọ́lẹ̀ lè jẹ́ èyí tí Ọlọ́run kò rán wa láti gbé rárá. A ò bá jọ̀wọ́ ẹrù wúwo yìí. Jẹ́ kí a rin ìrìn àjò tó fúyẹ́.
![Àlàáfíà tó Sonù](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F23174%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Àlàáfíà tó Sonù
Ọjọ́ Méje
N jẹ́ ó ṣeéṣẹ nítòótọ́ láti ní ìrírí àlàáfíà nígbàtí ayé kún fún ìnira? Ìdáhùn kúkúrú ni: Bẹ́ẹni, ṣùgbọ́n kìí ṣe nípa agbára wa. Nínú ọdún tó ti sọ wá di bíi ẹni tí a lù bolẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wa la kún fún ìbéèrè. Nínú Ètò Ẹ̀kọ́ Bíbélì olójọ́ méje yìí, tí wọ́n pẹ̀lú àwọn ìwàásù Oníwàásù Craig Groeschel, a ó ṣàwárí bí a ti leè rí àlàáfíà tó sọnù tí gbogbo wa ń pọ̀ùngbẹ.