← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Owe 8:14
Ìtàn Nípa Ọgbọn Ọlọrun
7 Awọn ọjọ
Ọgbọn lati Ọrun jẹ ẹbùn Ọlọrun fún wà láti mọ ohun to jẹ ti Ọlọ́run to tọ ati òhún ti o tọ, níní oyè wọn ati gbígbé nípa wọn bi ofin. A ngbe nínú ayé tó kún fún ètò, ayineke, àrékérekè, irọ ati etekete satani, báwò ni wa ṣe lá gbogbo èyí já láì sí Ọgbọn Ọlọrun? Oba Solomoni lẹyin gbogbo ànfàní Ọrọ, Owo, Okiki, Ìmọ, ati irin re nínú itura ayé, ṣe àkòtàn Ọgbọn bi "ìbẹrù Olùwà"