← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Luk 3:16
Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere
Ọjọ́ mẹ́fà
Kíni òtítọ́? Àṣà ń gba irọ́ náà wọlé pé òtítọ́ jẹ́ odò, tó ńru tó sì ń ṣàn lọ pẹ̀lú àkókò. Ṣùgbọ́n òtítọ́ kìí ṣe odò-àpáta ni. Nínú rírú-omi òkun àwọn èrò tó fẹ́ bòwá mọ́lẹ̀, ètò yìí yóò rán ìdákọ̀ró-okàn wa lọ́wọ́ láti lè múlẹ̀-yóò sì fún ọ ní ìtọ́sọ́nà tó yanjú nínú rúkè-rúdò ayé.