← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Luk 16:13
Ààyè Ìsinmi
Ọjọ́ 5
Ǹjẹ́ ó máa ń rí lára ni ìgbàkígbà wipé ó kò gbádùn ohunkóhun nítorí ó ñ gbìyànjú láti se gbogbo ohun? Ó nse opọ̀ nǹkan lẹ́ẹ̀kan nipase ònà rè ni ayé pèlú àwon ololufe rè. . .Ó jafafa. Sùgbọ́n ó n sàárẹ̀. Ó kan ní-lò àyè èémi die. Pèlú ipèwá sókí onìyàlénu kan, Olórun pèsè ònà láti ropo ìyára rè to dùn kọjá ààlà fun èyí to ma mu àlàáfíà wa ni ìkẹyìn. Ètò yìí ma fi báwo hàn é.