← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Luk 11:10
Àdúrà
Ọjọ́ Mọ́kànlé-Lógún
Kọ́ bí ó ṣe dára jùlọ láti gbàdúrà, láti inú ádùrá àwọn olódodo àti láti àwọn ọ̀rọ̀ Jésù fún rara Rẹ̀. Wá ìwúrí láti máa mú àwọn ìbéèrè rẹ lọ sí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run l'ójoojúmọ́, pẹ̀lú ìtẹramọ́ṣẹ́ àti sùúrù. Ṣ'àwárí àwọn àpẹẹrẹ ádùrá òfo, òdodo ti ara ẹni, èyí tí ó ṣe déédé sí àwọn ádùrá mímọ́ ti àwọn tí ó ní ọkàn mímọ́. Gbàdúrà nígbà gbogbo.