← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Joh 10:11
Gbogbo Ǹkan Tí Mo Nílò
Ọjọ́ Mẹ́ta
Ọlọ́run ti lọ ṣáájú wa ó sì ń pa wá mọ́ ní ọwọ́ ẹ̀yìn. Gbogbo ìdojúkọ wa ló ti yanjú. Gbogbo àlàfo ìdojúkọ ló sì ti dí pẹ̀lú. Ìpèníjà kò lè dé bá a lójijì. Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì ọlọ́jọ́-mẹ́ta yìí ma gbà ẹ́ ní ìyànjú nípa òtítọ́ wípé Ọlọ́run ni Olùpèsè ohun tó tọ́, àti èyí tó yẹ, fún ìgbésí ayé rẹ.