← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Gẹn 50:19

Gbígbẹ́ Ayé Ọ̀tun: Ní Ọdún Tuntun
Ọjọ́ 4
Ọdún Tuntun kọ̀ọ̀kan máa ń fún ni ní àǹfàní tuntun láti bẹ̀rẹ̀ ní ọ̀tun. Má ṣe jẹ́ kí ọdún yìí rí bíi ti àtẹ̀yìnwá pẹ̀lú àwọn ìpinnu tí o kò ní mú ṣẹ. Ètò ọlọ́jọ́ mẹ́rin yìí yóò ràn ọ́ l'ọ́wọ́ láti ronú jinlẹ̀ yóò sì fún ọ ní ìwòye tuntun kí o baà lè sọ ọdún yìí di ọdún tí ó dára jù lọ fún ọ.