Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Efe 5:24
![Kristi ninu Awọn ibatan - Apa kini](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F49852%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Kristi ninu Awọn ibatan - Apa kini
3 Awọn ọjọ
Ìfọkànsìn wa ń wá ọ̀nà láti fi ìlànà Pọ́ọ̀lù hàn nípa ìtẹríba láàárín àwọn ọkọ àti aya, àwọn òbí àti àwọn ọmọ, nígbà náà, àwọn ọ̀gá àti ìránṣ. Lẹhinna a yoo wo inu igbesi aye Jesu Kristi gẹgẹbi apẹẹrẹ pipe fun ijọsin lati farawe ninu awọn ibatan, nikẹhin, a yoo wo awọn adehun ti ọkunrin si iyawo rẹ ati ni idakeji. Adura mi ni pe ki ifọkansin yii yoo tan imọlẹ diẹ sii ni awọn agbegbe ti a nilo imọlẹ lori koko-ọrọ ni orukọ Jesu.
![Ìgbéyàwó Gẹ́gẹ́ Bí Ọlọ́run Ṣe Pète Rẹ̀](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F50501%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Ìgbéyàwó Gẹ́gẹ́ Bí Ọlọ́run Ṣe Pète Rẹ̀
3 Awọn ọjọ
Yálà ó ti ṣègbéyàwó tàbí o fẹ́ ṣe ìgbéyàwó, ìlànà kíkà ọlọ́jọ́-mkta yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe àwárí ètò rere Ọlọ́run fún ìfarajìn títí-ayé fún ọkọ àti aya. Kọ́ bí a ti ń ṣe àfihàn ìfẹ́ Jesu fún ìyàwó Rẹ̀, ìjọ, nípa ṣíṣe àwàjinlẹ̀ àwọn kókó bí i ìbádọ́rẹ̀ẹ́, ìbímọ, ìjẹ́rìí, ìjẹ́-mímọ́, àti ìgbádùn.
![Ẹ̀jẹ́ Náà](/_next/image?url=https%3A%2F%2F%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F4265%2F640x360.jpg&w=1920&q=75)
Ẹ̀jẹ́ Náà
Ọjọ́ mẹ́fà
Nínú Ètò Bíbélì Life.Church yí, àwọn l'ọkọ l'áya (tọkọtaya) mẹ́fà kọ nípa májẹ̀mú ìgbéyàwó tí wọn kò ní àǹfààní láti kà níwájú pẹpẹ. Àwọn májẹ̀mú ìpalémọ, oun-tó-ṣe-pàtàkì, ìlépa, àjọṣepọ̀, àìlábàwón, àdúrà ni májẹ̀mú tí ó máa ń mú ìgbéyàwó lọ létòletò kọjá àkókò adùn ayẹyẹ ìgbéyàwó. Bóyá o ti gbéyàwó tàbí o kò ì tí gbéyàwó, àkókò ti tó láti dá májẹ̀mú