← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú I. A. Ọba 14

Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (July)
Ọjọ́ Mòkanlé lọgbọ̀n
Apá keje ti onipin méjìlá, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 367. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá keje ní àwọn Iwé Samueli Kejì, Àwọn Ọba kínní àti èkejì, pẹlu Maku.