← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú I. Joh 2:3
Ìgbọ́ràn
2 Ọ̀sẹ̀
Jésù fún rara Rẹ̀ sọ wípé ẹnikẹ́ni tí ó fẹ́ràn Rẹ̀ yóò gbọ́ràn sí ẹ̀kọ́-o Rẹ̀. Láì bìkítà ohun tí ó ba ná wa, ìgbọ́ràn wa ṣe pàtàkì sí Ọlọ́run. Ètò yìí sọ̀rọ̀ lórí ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ nípa ìgbọ́ràn: Bí a ṣe lè ṣẹ̀ ìtọ́jú ìṣàrò ìdúróṣinṣin, ipa àánú, bí ìgbọ́ràn ṣe tú wa sílẹ̀ àti bùkún ayé wa, àti diẹ sii.