1
Mak 15:34
Bibeli Mimọ
Ni wakati kẹsan ni Jesu si kigbe soke li ohùn rara, wipe, Eloi, Eloi, lama sabaktani? itumọ eyi ti ijẹ, Ọlọrun mi, Ọlọrun mi, ẽṣe ti iwọ fi kọ̀ mi silẹ?
Comparar
Explorar Mak 15:34
2
Mak 15:39
Nigbati balogun ọrún, ti o duro niha ọdọ rẹ̀ ri ti o kigbe soke bayi, ti o si jọwọ ẹmi rẹ̀ lọwọ, o wipe, Lõtọ Ọmọ Ọlọrun li ọkunrin yi iṣe.
Explorar Mak 15:39
3
Mak 15:38
Aṣọ ikele tẹmpili si ya si meji lati oke de isalẹ.
Explorar Mak 15:38
4
Mak 15:37
Jesu si kigbe soke li ohùn rara, o jọwọ ẹmi rẹ̀ lọwọ.
Explorar Mak 15:37
5
Mak 15:33
Nigbati o di wakati kẹfa, òkunkun si ṣú bò gbogbo ilẹ titi o fi di wakati kẹsan.
Explorar Mak 15:33
6
Mak 15:15
Pilatu si nfẹ se eyi ti o wù awọn enia, o da Barabba silẹ fun wọn. Nigbati o si nà Jesu tan, o fà a le wọn lọwọ lati kàn a mọ agbelebu.
Explorar Mak 15:15
Início
Bíblia
Planos
Vídeos