1
Mat 22:37-39
Bibeli Mimọ
Jesu si wi fun u pe, Ki iwọ ki o fi gbogbo àiya rẹ, ati gbogbo ọkàn rẹ, ati gbogbo inu rẹ, fẹ́ Ọlọrun Oluwa rẹ. Eyi li ekini ati ofin nla. Ekeji si dabi rẹ̀, Iwọ fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ.
Comparar
Explorar Mat 22:37-39
2
Mat 22:40
Ninu awọn ofin mejeji yi ni gbogbo ofin ati wolĩ rọ̀ mọ́.
Explorar Mat 22:40
3
Mat 22:14
Nitori ọ̀pọlọpọ li a pè, ṣugbọn diẹ li a yàn.
Explorar Mat 22:14
4
Mat 22:30
Nitoripe li ajinde okú, nwọn kì igbeyawo, a kì si fi wọn funni ni igbeyawo, ṣugbọn nwọn dabi awọn angẹli Ọlọrun li ọrun.
Explorar Mat 22:30
5
Mat 22:19-21
Ẹ fi owodẹ kan hàn mi. Nwọn si mu owo idẹ kan tọ̀ ọ wá. O si bi wọn pe, Aworan ati akọle tali eyi? Nwọn wi fun u pe, Ti Kesari ni. Nigbana li o wi fun wọn pe, Njẹ ẹ fi ohun ti iṣe ti Kesari fun Kesari, ati ohun ti iṣe ti Ọlọrun fun Ọlọrun.
Explorar Mat 22:19-21
Início
Bíblia
Planos
Vídeos