1
Gẹnẹsisi 25:23
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA sì wí fún un pé, “Orílẹ̀-èdè méjì ni ń bẹ nínú rẹ, irú ènìyàn méjì ni yóò yà láti inú rẹ; àwọn ènìyàn kan yóò jẹ́ alágbára ju èkejì lọ, ẹ̀gbọ́n ni yóò máa sin àbúrò.”
Bandingkan
Selidiki Gẹnẹsisi 25:23
2
Gẹnẹsisi 25:30
Esau wí fún Jakọbu pé, “Èmí bẹ̀ ọ, fi ìpẹ̀tẹ̀ rẹ pupa n nì bọ́ mi, nítorí tí ó rẹ̀ mí gidigidi.” (Nítorí náà ni a ṣe ń pe orúkọ rẹ̀ ní Edomu).
Selidiki Gẹnẹsisi 25:30
3
Gẹnẹsisi 25:21
Isaaki sì gbàdúrà sì OLúWA, nítorí aya rẹ̀ tí ó yàgàn, OLúWA sì gbọ́ àdúrà rẹ̀, Rebeka sì lóyún.
Selidiki Gẹnẹsisi 25:21
4
Gẹnẹsisi 25:32-33
Esau sì dáhùn pé, “Wò ó mo ti fẹ́rẹ kú, àǹfààní kín sì ni ogún ìbí jẹ́ fún mi?” Ṣùgbọ́n, Jakọbu dáhùn pé, “Kọ́kọ́ búra fún mi pé tèmi ni ogún ìbí náà yóò jẹ́.” Báyìí ni Esau búra tí ó sì gbé ogún ìbí rẹ̀ tà fún Jakọbu.
Selidiki Gẹnẹsisi 25:32-33
5
Gẹnẹsisi 25:26
Lẹ́yìn èyí ni arákùnrin èkejì jáde wá, ọwọ́ rẹ̀ sì di Esau ni gìgísẹ̀ mú, nítorí náà ni wọn ṣe pe orúkọ rẹ ni Jakọbu. Ọmọ ọgọ́ta ọdún ni Isaaki, nígbà tí Rebeka bí wọn.
Selidiki Gẹnẹsisi 25:26
6
Gẹnẹsisi 25:28
Isaaki, ẹni tí ó fẹ́ràn ẹran igbó fẹ́ràn Esau nítorí ẹran igbó tí Esau máa ń pa, ṣùgbọ́n Rebeka fẹ́ràn Jakọbu.
Selidiki Gẹnẹsisi 25:28
Halaman Utama
Alkitab
Pelan
Video