JẸNẸSISI 11:1

JẸNẸSISI 11:1 YCE

Nígbà kan èdè kan ṣoṣo ni ó wà láyé, ọ̀rọ̀ bíi mélòó kan ni gbogbo wọ́n sì ń lò.