1
Gẹnẹsisi 2:24
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí ìdí èyí, ọkùnrin yóò fi baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóò sì dàpọ̀ mọ́ aya rẹ̀, wọn yóò sì di ara kan.
Bandingkan
Telusuri Gẹnẹsisi 2:24
2
Gẹnẹsisi 2:18
OLúWA Ọlọ́run wí pé, “Kò dára kí ọkùnrin wà ní òun nìkan. Èmi yóò ṣe olùrànlọ́wọ́ tí ó rí bí i rẹ̀ fún un.”
Telusuri Gẹnẹsisi 2:18
3
Gẹnẹsisi 2:7
OLúWA Ọlọ́run sì fi erùpẹ̀ ilẹ̀ mọ ènìyàn, ó si mí èémí ìyè sí ihò imú rẹ̀, ènìyàn sì di alààyè ọkàn.
Telusuri Gẹnẹsisi 2:7
4
Gẹnẹsisi 2:23
Ọkùnrin náà sì wí pé, “Èyí ni egungun láti inú egungun mi àti ẹran-ara nínú ẹran-ara mi; ‘obìnrin’ ni a ó máa pè é, nítorí a mú un jáde láti ara ọkùnrin.”
Telusuri Gẹnẹsisi 2:23
5
Gẹnẹsisi 2:3
Ọlọ́run sì súre fún ọjọ́ keje, ó sì yà á sí mímọ́, nítorí pé ní ọjọ́ náà ni ó sinmi kúrò nínú iṣẹ́ dídá ayé tí ó ti ń ṣe.
Telusuri Gẹnẹsisi 2:3
6
Gẹnẹsisi 2:25
Ọkùnrin náà àti aya rẹ̀ sì wà ní ìhòhò, ojú kò sì tì wọ́n.
Telusuri Gẹnẹsisi 2:25
Beranda
Alkitab
Rencana
Video