1
JẸNẸSISI 7:1
Yoruba Bible
Nígbà tí ó yá OLUWA sọ fún Noa pé, “Wọ inú ọkọ̀ lọ, ìwọ ati àwọn ará ilé rẹ, nítorí pé ìwọ nìkan ni o jẹ́ olódodo sí mi ní gbogbo ayé.
Bandingkan
Telusuri JẸNẸSISI 7:1
2
JẸNẸSISI 7:24
Aadọjọ (150) ọjọ́ gbáko ni omi fi bo gbogbo ilẹ̀.
Telusuri JẸNẸSISI 7:24
3
JẸNẸSISI 7:11
Ní ọjọ́ kẹtadinlogun oṣù keji ọdún tí Noa di ẹni ẹgbẹta (600) ọdún, ni orísun alagbalúgbú omi tí ó wà ninu ọ̀gbun ńlá lábẹ́ ilẹ̀ ya, tí gbogbo fèrèsé omi tí ó wà ní ojú ọ̀run ṣí sílẹ̀
Telusuri JẸNẸSISI 7:11
4
JẸNẸSISI 7:23
Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe pa gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó wà láyé run: gbogbo eniyan, gbogbo ẹranko, gbogbo ohun tí ń rìn káàkiri lórí ilẹ̀ ati ẹyẹ. Noa nìkan ni kò kú ati àwọn tí wọ́n jọ wà ninu ọkọ̀ pẹlu rẹ̀.
Telusuri JẸNẸSISI 7:23
5
JẸNẸSISI 7:12
òjò sì rọ̀ fún ogoji ọjọ́, tọ̀sán-tòru.
Telusuri JẸNẸSISI 7:12
Beranda
Alkitab
Rencana
Video