JOHANU 6:19-20

JOHANU 6:19-20 YCE

Lẹ́yìn tí wọ́n ti wa ọkọ̀ bí ibùsọ̀ mẹta tabi mẹrin wọ́n rí Jesu, ó ń rìn lórí òkun, ó ti súnmọ́ etí ọkọ̀ wọn. Ẹ̀rù bà wọ́n. Ṣugbọn ó wí fún wọn pé, “Èmi ni. Ẹ má bẹ̀rù.”

Read JOHANU 6