1
Gẹn 2:24
Bibeli Mimọ
Nitori na li ọkunrin yio ṣe ma fi baba on iya rẹ̀ silẹ, yio si fi ara mọ́ aya rẹ̀: nwọn o si di ara kan.
Compare
Explore Gẹn 2:24
2
Gẹn 2:18
OLUWA Ọlọrun si wipe, kò dara ki ọkunrin na ki o nikan ma gbé; emi o ṣe oluranlọwọ ti o dabi rẹ̀ fun u.
Explore Gẹn 2:18
3
Gẹn 2:7
OLUWA Ọlọrun si fi erupẹ ilẹ mọ enia; o si mí ẹmí ìye si ihò imu rẹ̀; enia si di alãye ọkàn.
Explore Gẹn 2:7
4
Gẹn 2:23
Adamu si wipe, Eyiyi li egungun ninu egungun mi, ati ẹran-ara ninu ẹran-ara mi: Obinrin li a o ma pè e, nitori ti a mu u jade lati ara ọkunrin wá.
Explore Gẹn 2:23
5
Gẹn 2:3
Ọlọrun si busi ijọ́ keje, o si yà a si mimọ́; nitori pe, ninu rẹ̀ li o simi kuro ninu iṣẹ rẹ̀ gbogbo ti o ti bẹ̀rẹ si iṣe.
Explore Gẹn 2:3
6
Gẹn 2:25
Awọn mejeji si wà ni ìhoho, ati ọkunrin na ati obinrin rẹ̀, nwọn kò si tiju.
Explore Gẹn 2:25
હોમ
બાઇબલ
યોજનાઓ
વિડિઓઝ