YouVersion Logo
Search Icon

Est Ọ̀rọ̀ Iṣaaju

Ọ̀rọ̀ Iṣaaju
Ìwé Ẹsteri jẹ́ ìtàn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ní ilé tí ọba Persia máa ń gbé ní ìgbà òtútù. Ìtàn inú ìwé náà dá lórí Ẹsteri, akọni obinrin, ayaba, ọmọ ilẹ̀ Juu. Ó gba àwọn eniyan rẹ̀ là lọ́wọ́ ìparun àwọn ọ̀tá wọn, nítorí ẹ̀mí ìgboyà ati ìfẹ́ àwọn eniyan rẹ̀ tí ó ní, láìbìkítà bí òun kú, bí òun yè. Ìwé yìí ṣe àlàyé ìtumọ̀ ọdún Purimu tí àwọn Juu máa ń ṣe, ati bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀.
Àwọn Ohun tí ó wà ninu Ìwé yìí ní Ìsọ̀rí-ìsọ̀rí
Ẹsteri di ayaba 1:1—2:23
Àwọn ọ̀tẹ̀ tí Hamani dì 3:1—5:14
Ikú Hamani 6:1—7:10
Àwọn Juu ṣẹgun àwọn ọ̀tá wọn 8:1—10:3

Currently Selected:

Est Ọ̀rọ̀ Iṣaaju: YBCV

Highlight

Share

Copy

None

Want to have your highlights saved across all your devices? Sign up or sign in