YouVersion Logo
Search Icon

ORIN DAFIDI 134

134
Ẹ yin OLUWA
1Ẹ wá, ẹ yin OLUWA,
gbogbo ẹ̀yin iranṣẹ rẹ̀,
gbogbo ẹ̀yin tí ń sìn ín ninu ilé rẹ̀ lóru.
2Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè, kí ẹ gbadura ninu ilé mímọ́ rẹ̀,
kí ẹ sì yin OLUWA.
3Kí OLUWA tí ó dá ọ̀run ati ayé
bukun yín láti Sioni wá.

Currently Selected:

ORIN DAFIDI 134: YCE

Highlight

Share

Copy

None

Want to have your highlights saved across all your devices? Sign up or sign in