1
Òwe 15:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìdáhùn pẹ̀lẹ́ yí ìbínú padà ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ líle máa ń ru ìbínú sókè.
Compare
Explore Òwe 15:1
2
Òwe 15:33
Ìbẹ̀rù OLúWA kọ́ ènìyàn ní ọgbọ́n, Ìrẹ̀lẹ̀ sì ni ó máa ń ṣáájú ọlá.
Explore Òwe 15:33
3
Òwe 15:4
Ahọ́n tí ń mú ìtura wá jẹ́ igi ìyè ṣùgbọ́n ahọ́n ẹ̀tàn ń pa ẹ̀mí run.
Explore Òwe 15:4
4
Òwe 15:22
Ìgbèrò a máa dasán níbi tí kò sí ìmọ̀ràn; ṣùgbọ́n a máa yege níbi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùbádámọ̀ràn wà.
Explore Òwe 15:22
5
Òwe 15:13
Inú dídùn máa ń mú kí ojú túká ṣùgbọ́n ìbànújẹ́ ọkàn máa ń pa ẹ̀mí run.
Explore Òwe 15:13
6
Òwe 15:3
Ojú OLúWA wà níbi gbogbo, Ó ń wo àwọn ẹni búburú àti àwọn ẹni rere.
Explore Òwe 15:3
7
Òwe 15:16
Ó sàn kí ó má pọ̀, kí ìbẹ̀rù OLúWA sì wà ju ọrọ̀ púpọ̀ pẹ̀lú ìyọnu.
Explore Òwe 15:16
8
Òwe 15:18
Ènìyàn onínú ríru dá ìjà sílẹ̀ ṣùgbọ́n onísùúrù paná ìjà.
Explore Òwe 15:18
9
Òwe 15:28
Ọkàn olódodo ń wọn ìdáhùn wò ṣùgbọ́n ẹnu ènìyàn búburú ń tú ibi jáde.
Explore Òwe 15:28
Home
Bible
Plans
Videos