1
Amosi 5:24
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ́ kí òtítọ́ sàn bí odò àti òdodo bí ìsun tí kò lé è gbẹ!
Compare
Explore Amosi 5:24
2
Amosi 5:14
Wá rere, má ṣe wá búburú kí ìwọ ba à le yè Nígbà náà ni OLúWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun yóò wà pẹ̀lú rẹ. Òun yóò sì wà pẹ̀lú rẹ bí ìwọ ṣe wí
Explore Amosi 5:14
3
Amosi 5:15
Kórìíra búburú kí o sì fẹ́ rere dúró ní orí òtítọ́ ní ilé ẹjọ́ bóyá OLúWA Ọlọ́run alágbára yóò ṣíjú àánú wo ọmọ Josẹfu tó ṣẹ́kù.
Explore Amosi 5:15
4
Amosi 5:4
Èyí ni ohun tí OLúWA sọ fún ilé Israẹli: “Wá mi kí o sì yè
Explore Amosi 5:4
Home
Bible
Plans
Videos