1
Amosi 4:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹni tí ó dá àwọn òkè tí ó dá afẹ́fẹ́ tí ó sì fi èrò rẹ̀ hàn sí ènìyàn, ẹni tí ó yípadà sí òkùnkùn tí ó sì tẹ ibi gíga ayé. OLúWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀.
Compare
Explore Amosi 4:13
2
Amosi 4:12
“Nítorí náà, èyí ni ohun tí èmi yóò ṣe sí i yín, Israẹli, àti nítorí tí èmi ó ṣe èyí sí i yín, ẹ múra láti pàdé Ọlọ́run yín, ẹ̀yin Israẹli.”
Explore Amosi 4:12
3
Amosi 4:6
“Èmi fún un yín ní mímọ́ eyín ní gbogbo ìlú yín, àti àìní oúnjẹ ní gbogbo ibùgbé yín, síbẹ̀, ẹ̀yin kò yípadà sọ́dọ̀ mi,” ni OLúWA wí.
Explore Amosi 4:6
Home
Bible
Plans
Videos