1
2 Ọba 19:19
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nísinsin yìí OLúWA Ọlọ́run wa, gbà wá kúrò lọ́wọ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn ìjọba lórí ilẹ̀ ayé le mọ̀ pé ìwọ nìkan ṣoṣo ni, OLúWA Ọlọ́run wa.”
Compare
Explore 2 Ọba 19:19
2
2 Ọba 19:15
Hesekiah gbàdúrà sí OLúWA: “OLúWA Ọlọ́run Israẹli, tí ń gbé ní àárín àwọn kérúbù, ìwọ nìkan ni Ọlọ́run lórí gbogbo ìjọba tí ó wà láyé, ìwọ ti dá ọ̀run àti ayé.
Explore 2 Ọba 19:15
Home
Bible
Plans
Videos