1
2 Ọba 18:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Hesekiah sì gbẹ́kẹ̀lé OLúWA Ọlọ́run Israẹli. Kò sì ṣí ẹnìkan tí ó dàbí tirẹ̀ lára gbogbo àwọn ọba Juda, bóyá kí ó tó jẹ tàbí lẹ́yìn rẹ̀.
Compare
Explore 2 Ọba 18:5
2
2 Ọba 18:6
Ó súnmọ́ OLúWA, kò sì dẹ́kun láti tì í lẹ́yìn: ó sì pa òfin OLúWA mọ́ tí ó ti fi fún Mose.
Explore 2 Ọba 18:6
3
2 Ọba 18:7
OLúWA sì wà pẹ̀lú rẹ̀; ó sì ń ṣe rere nínú gbogbo ohun tí ó dáwọ́lé. Ó ṣe ọ̀tẹ̀ sí ọba Asiria kò sì sìn ín.
Explore 2 Ọba 18:7
Home
Bible
Plans
Videos