1
I. Kro 16:11
Bibeli Mimọ
Ẹ ma wá Oluwa, ati ipa rẹ̀, ma wá oju rẹ̀ nigbagbogbo.
Compare
Explore I. Kro 16:11
2
I. Kro 16:34
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa, nitori ti o ṣeun: nitoriti ãnu rẹ̀ duro lailai.
Explore I. Kro 16:34
3
I. Kro 16:8
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa, ẹ pè orukọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ rẹ̀ hàn ninu awọn enia.
Explore I. Kro 16:8
4
I. Kro 16:10
Ẹ ma ṣogo li orukọ rẹ̀ mimọ́; jẹ ki ọkàn awọn ti nwá Oluwa ki o yọ̀.
Explore I. Kro 16:10
5
I. Kro 16:12
Ẹ ma ranti iṣẹ iyanu rẹ̀ ti o ti ṣe, iṣẹ àmi rẹ̀, ati idajọ ẹnu rẹ̀
Explore I. Kro 16:12
6
I. Kro 16:9
Ẹ kọrin si i, ẹ kọ́ orin mimọ́ si i, ẹ ma sọ̀rọ gbogbo iṣẹ iyanu rẹ̀.
Explore I. Kro 16:9
7
I. Kro 16:25
Nitori titobi li Oluwa, o si ni iyìn gidigidi: on li o si ni ibẹ̀ru jù gbogbo oriṣa lọ.
Explore I. Kro 16:25
8
I. Kro 16:29
Ẹ fi ogo fun Oluwa ti o yẹ fun orukọ rẹ̀: mu ọrẹ wá, ki ẹ si wá siwaju rẹ̀: ẹ sin Oluwa ninu ẹwà ìwa-mimọ́.
Explore I. Kro 16:29
9
I. Kro 16:27
Ogo on ọlá wà niwaju rẹ̀; agbara ati ayọ̀ mbẹ ni ipò rẹ̀.
Explore I. Kro 16:27
10
I. Kro 16:23
Ẹ kọrin titun si Oluwa gbogbo aiye; ẹ ma fi igbala rẹ̀ hàn lati ọjọ de ọjọ.
Explore I. Kro 16:23
11
I. Kro 16:24
Ẹ sọ̀rọ ogo rẹ̀ ninu awọn keferi; ati iṣẹ-iyanu rẹ̀ ninu gbogbo enia.
Explore I. Kro 16:24
12
I. Kro 16:22
Wipe, Ẹ má ṣe fi ọwọ kan ẹni-ororo mi, ẹ má si ṣe awọn woli mi ni ibi.
Explore I. Kro 16:22
13
I. Kro 16:26
Nitori pe gbogbo oriṣa awọn enia, ere ni nwọ́n: ṣugbọn Oluwa li o da awọn ọrun.
Explore I. Kro 16:26
14
I. Kro 16:15
Ẹ ma ṣe iranti majẹmu rẹ̀ titi lai, ọ̀rọ ti o ti pa li aṣẹ fun ẹgbẹrun iran
Explore I. Kro 16:15
15
I. Kro 16:31
Jẹ ki awọn ọrun ki o yọ̀, si jẹ ki inu aiye ki o dùn; si jẹ ki a wi ninu awọn orilẹ-ède pe, Oluwa jọba.
Explore I. Kro 16:31
16
I. Kro 16:36
Olubukún li Oluwa Ọlọrun Israeli lai ati lailai. Gbogbo awọn enia si wipe, Amin, nwọn si yìn Oluwa.
Explore I. Kro 16:36
17
I. Kro 16:28
Ẹ fi fun Oluwa, ẹnyin ibatan enia, ẹ fi ogo ati ipa fun Oluwa.
Explore I. Kro 16:28
Home
Bible
Plans
Videos