1
ÀWỌN ỌBA KEJI 19:19
Yoruba Bible
Nisinsinyii OLUWA Ọlọrun wa, jọ̀wọ́ gbà wá lọ́wọ́ Asiria kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé lè mọ̀ pé ìwọ OLUWA nìkan ni ỌLỌRUN.”
Compare
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 19:19
2
ÀWỌN ỌBA KEJI 19:15
Ó gbadura pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ń gbé láàrin àwọn Kerubu, ìwọ nìkan ni Ọlọrun tí ń jọba lórí gbogbo ilẹ̀ ayé, ìwọ ni o dá ayé ati ọ̀run.
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 19:15
Home
Bible
Plans
Videos