1
ÀWỌN ỌBA KEJI 18:5
Yoruba Bible
Hesekaya ní igbagbọ ninu OLUWA Ọlọrun Israẹli. Juda kò sì ní ọba mìíràn tí ó dà bíi rẹ̀, yálà ṣáájú rẹ̀ ni, tabi lẹ́yìn rẹ̀.
Compare
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 18:5
2
ÀWỌN ỌBA KEJI 18:6
Ó jẹ́ olóòótọ́ sí OLUWA, kò yapa kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, ṣugbọn ó fi tọkàntọkàn pa àwọn òfin tí OLUWA fún Mose mọ́.
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 18:6
3
ÀWỌN ỌBA KEJI 18:7
OLUWA wà pẹlu rẹ̀, ó sì ń ṣe àṣeyọrí ninu gbogbo ohun tí ó ń ṣe. Ó gba ara rẹ̀ lọ́wọ́ ọba Asiria, ó di òmìnira, ó kọ̀ kò sìn ín mọ́.
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 18:7
Home
Bible
Plans
Videos