Joh 6:19-20
Joh 6:19-20 YBCV
Nigbati nwọn wà ọkọ̀ to bi ìwọn furlongi mẹdọgbọn tabi ọgbọ̀n, nwọn ri Jesu nrìn lori okun, o si sunmọ ọkọ̀; ẹ̀ru si bà wọn. Ṣugbọn o wi fun wọn pe, Emi ni; ẹ má bẹ̀ru.