1
Gẹn 10:8
Bibeli Mimọ
Kuṣi si bí Nimrodu: on si bẹ̀rẹ si idi alagbara li aiye.
對照
Gẹn 10:8 探索
2
Gẹn 10:9
On si ṣe ogbóju ọdẹ niwaju OLUWA: nitori na li a ṣe nwipe, Gẹgẹ bi Nimrodu ogbóju ọdẹ niwaju OLUWA.
Gẹn 10:9 探索
主頁
聖經
計劃
影片