圣经译本

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

Yoruba

Ajọ Biblica, The International Bible Society, ń pèsè ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fún àwọn ènìyàn nípa títúmọ̀, títa Bíbélì jáde jákèjádò orílẹ̀-èdè Afíríkà, Asia, Pacific, Europe, Latin America, Middle East àti North America. Àjọ Bíbílíkà ń mú kí àwọn ènìyàn ayé bá Ọlọ́run pàdé nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀, láti yí ìgbé ayé wọn padà nípasẹ̀ ìbásepọ̀ àti àjọdàpọ̀ wọn pẹ̀lú Jesu Kristi.


Biblica, Inc.

YCB 出版者

获取更多信息

Biblica, Inc.发行的其他译本