Ọlọrun, Èmi Ńkọ́?Àpẹrẹ
Dójú ti Èṣù!
Dójú ti Èṣù! Fi ojú rẹ̀ gbo lẹ̀ pẹ̀lú ìgbàgbó rẹ. Fi ìgbésí ayé rẹ yẹ̀yẹ́ rẹ̀. Jẹ́ kí ó ma bèèrè ìdí tí ó fi wá ba ìkan jẹ́. Jẹ́ kí ó Jẹ́ ìtìjú fun pé ó kọlu ọkàn rẹ. Lúu padà pẹ̀lú gbígba àdúrà láì woo ìrora, nípa ṣíṣe ètò láì bìkítà ìjá ku lè, nípa níní ìgbàgbó láì bìkítà ohun tí ojú rẹ rí.
Èṣù wà lẹ́yìn ìgbàgbó wa. Kò bìkítà nípa àwọn ẹbí rẹ, ọkọ̀, ìlera, ẹ̀kọ́ àti bẹ́ẹ̀ lọ. Ó fẹ́ láti pa ìgbàgbó rẹ. Èyí ni ọ̀nà tí ó gbà láti pa, jalè àti parun.
Rántí pé Ọlọ́run pàdé wà nínu ìjìyà! Jẹ́ kí Èyí àsìkò tí o ma ṣe à wà jinlẹ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run. Ní ìrírí rẹ̀ fún ọrẹ fẹ́ láti pọ̀ sí. Ìwọ yóò lọ sí iwájú Ọlọ́run láti wá iṣẹ́, ọkọ̀ titun, láti ṣe ìgbéyàwó, ìwòsàn fún ara rẹ, wà si ri pé ìwọ yíò jáde pẹ̀lú ohun tí ó tún dára jùlọ Ní iwájú rẹ.
Níní ìgbàgbó leè mú kí ìwọ nìkan dá wà. Ó le mú kí o dàbí ẹni tí ko mọn ìkankan, asiwèrè àti laáyì lọ́gbọ́n. Gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin ọlọgbón ṣe wí "Mọ le má Mọ oun tí ọ̀la jẹ́ ṣùgbọ́n mo mọ ẹni tí ó mú ọjọ́ ọ̀la dání àti pé ó ṣì di owó mi mú."
Kò jẹ́ kí ohun kóhun di lọ́wọ́ láti gba èmi rẹ là, nítorí náà o le ní ìgbàgbó nínu rẹ̀ pé dájúdájú wípé ó sọ wípé òun ki yíò fi ọ sílè.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Nígbà tá a bá rò pé a ti jìnnà síbi tá a yẹ ká máa gbé, tí ohùn ìfiwéra sì túbọ̀ ń dún bí ọjọ́ ti ń gorí ọjọ́, a kì í sábà rí i pé Ọlọ́run wà láàárín wa. Àwọn àkókò yìí gan-an ni ìgbàgbọ́ wa máa ń lágbára jù lọ. Ka àdúrà yìí kó o sì rí ìṣírí gbà bó o ṣe ń dúró de Ọlọ́run.
More