Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Ìmólè Tí Dé
Kérésìmesì tí dé! Àkókò tí dé láti sàjoyò ìbí Olùgbàlà wa, Jésù Kristi— Ìmólè Ayé!
Ní ìse àkókó tí Ìsèdá ní Jénésísí, Olórun sòrò àti ìmólè sí wá pínyà pèlú òkùnkùn lésèkesè. Àmó kò pé kí Ádámù àti Éfà tó yàn láti dá èsè, àti ìwaláàyè Olórun, ìmólè Rè, pínyà pèlú ènìyàn. Ní àsìkò náà, a ní láti ko ìtan ìgbàlà: Ìní-lò fún ìmólè láti tàn nípasè òkùnkùn kì i se alé àti òsán lásán, àmó ìyè àti ikú. Ifé Olórun nlá ní láti wa ní ìbáṣepò pèlú wa, nítorí náà Ó ràn Ìmólè láti satònà wa kúró nínú òkùnkùn wa àti padà sódó Rè.
Kérésìmesì Lèyí: “ Ènì tó jé ìmólè òtító, tó fún gbogbo èèyàn ní ìmólè, ń bọ̀ sínú ayé!”
A bí Omo Olórun kan soso tó jé pé pèlú ìdáríjì èsè, a lè làjà wa pèlú Olórun. Ìmólè Jésù ségun ìpínyà tó fi wa sí òkùnkùn. Jésù so pé, “Èmí ní ìmólè ayé; enikéni tó bá télè mi kò ní rìn nínú òkùnkùn láé, sùgbón yóò ní ìmólè ìyè.”
Ìbí yóò wu tó lè wa lónìí, àtipe ohun yóò wu tí o tí se, Olùgbàlà ayé tí dé! fún Ìwo! Jé kí ìmólè Rè tàn sórí gbogbo ibi tó sokùnkùn láyé rè àti ìdapadà bò sípò àwon ohun tó tí sonù sí òkùnkùn. Ìmólè wà níbí, àtipe Ó tí kéde pé ó kò ní láti rìn nínú òkùnkùn mo láé. Gbà ifé Rè àti ní ìrírí Kérésìmesì bí ó kò tí se ní télè.!
Àdúrà: Bàbá, E ṣeun fún ìpèsè ònà láti ìbèrè ìgbà fún wa láti tún sún mo Yín. E se pé E ràn Omo Yín pé kí a bí Omo Yín, àti láti kú, kí èmí lè gbé ayé! Lónìí, bí mo n se sàjoyò Kérésìmesì, E ràn mi lówó láti mọrírì ifé Yín fún mi tó jínlè àti Ìmólè Té tí mú wo inú ayé mi. Mo yin Yín pé E jé kí o seé se fún mi láti má tún rìn nínú òkùnkùn láé.!
Gbà àwòrán tónìí jáde níbí.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More