Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Ìlépa Ń Máa Yorí sí Ìdàgbàsòkè
Lúùkù 2:22 sò fún wa pé nígbà tí Jésù wa lomodé, Màríà àti Jósẹ́fù gbé wá sí tẹ́ńpìlì ni Jerúsálẹ́mù láti fi I fún Olórun àtipe bólá fún àwon òfin Olúwa. A wà ká pé Jésù dàgbà Ó sí dí olókun,Ó kún pèlú ogbón, àti oore ọ̀fẹ́ Olórun sí wà lórí Rè (láti ese 40).Jésù fi àpẹẹrẹ bí o se yé kí a gbé ìgbé ayé lélẹ̀, àmó ó lè dá bí pé kò seé se tí a bá fi àfiyèsí sórí ohun tó dájú gan nìkan soso pé Ó jé Olórun. Jésù jé ènìyàn ni kíkún, níbamú pèlú Ìwé Mímó kódà.Ó ní àǹfààní láti gbèrú àti dàgbà. Àmó kí lo mú kí Òlùgbàlà wa dàgbàsòkè?
Ní àṣà òde tónìí, a ní ìdojukọ lọ́tùn-ún-lósì wa pèlú ìpolówó ìrànlówó ara ènì tón sò fún wa bí a má se mú arawa lókun sí,se áṣeyọrí sí i nínú okòwò, ràn ara wa lówó láti borí ìsoríkọ́... Fún dólà díè péré, a lè kó mó àti tún see mó àti mú arawa se dáa dáa sí.
O se pàtàkì láti fi àfiyèsí sórí Òrò tó sòrò nípa ìṣẹlẹ̀ ìdàgbàsòkè Jésù bí Òun àti àwon ebí Rè ń ṣẹ bólá fún Olórun. Dájúdájú, àwon ìgbésẹ̀ wà tá lè gbà nínú òkun wa láti dàgbà, sùgbón kò sí iye ìrànlówó ara ènì tó lè tí mú Jésù gbára dì fún ìpè náà lórí ayé Rè. Àtipe kò sí iye ìrànlówó ara ènì tó lè gbà ipò oore ọ̀fẹ́ yálà nínú àwon ayé wa. A wo àwon Kristeni lórí ìbùsùn ikú pèlú ìmò ńlá àti òkun tó ju òpò àwon áṣeyọrí àtọwọ́dá ara ènì ti olórí tàbí àwon eléré ìdárayá lo. A kò jèrè ìmò àti òkun nípa gbígbìyànjú láti ràn ara wa lówó. Wón jé ìmújáde omìlépa àti bibólá fún Olórun àti nínírírí oore ọ̀fẹ́ Rè tón yí ayé ènì padà.
láàárín àkókò Kérésìmesì yìí, fi àfiyèsí sórí ohun tó seé se nígbà tí o ba sún mo Jésù. Ó kò ní láti tiraka láti kúnjú ìwọ̀n ìdíwòn tí ọwọ́ kò tí ì tó tí ayé. Simi ni mimò pé ìmò òtító àti òkun yóò wa láti ìsúnmọ́lé rè sí Olórun. Tó ba lépa È lójoojúmó, ìdánilójú wa láti dàgbà àti gbára di fún ète rè.
Àdúrà: Bàbá, E se fún jíjé orísun ìmò àti òkun mi. Oore ọ̀fẹ́ Yín fún mi ní ìretí fún ojó ìwájú mi.Mo mò pé E tóbi gidigidi gan ju bi mo se lè tóbi lo láé àtipe mo moore gan fún ìmúratán Yín láti pín òkun Yín pèlú mi. Nígbà tí mo ńbá tiraka, E ràn mi lówó láti gbára lè Yín dípò lè ara mi.
Gbà àwòrán tónìí jáde níbí.
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More