Bíbọ̀wá: Ìrìn Àjò Sí KérésìmesìÀpẹrẹ
Ènu yà àwon o ní Ìyàlẹ́nu
Se ó lè finú wòye ohun ti àwon olùṣọ́ àgùntàn ní ìrírí nígbàtí ẹgbẹ́ ogun tí “àwon ogun ọ̀run” Fara hàn ní asale Kérésìmesì? Won kúkú tọ́jú àwon àgùtàn won ní pápá kan, àtipe lójijì: òfurufú tó kún fún àwon ángèlì. O seé se kí won tí gbó nípa àwon ángèlì, àmó rírí i wón gan-an lè jé ohun méjèèjì didáyà jáni àti yíàlẹ́nu. finú wòye àwon ọgọrọọrun ángèlì n kígbe ìyìn papò láti mú ohun tó gbódò tí jé se fẹ́rẹ̀ẹ́ dini létí, ohùn ológo. Ohun àsìkò àràmàǹdà!
O lè jé pé àngèlì nìrísíye fún ìjosìn ni ètó won. Wón sí yàtò sí ohunkóhun ti a rí nibi lórí ayé, fifi ìlmọ́lẹ̀ òrun hàn, àti n páse àfiyèsí kikún àti ìbọ̀wọ̀ fún ènì. Sùgbón wón kì I se kókó ìjosìn. Gégé bí wón se jọni lójú gan-an, àwon àngèlì darí àfiyèsí pátápátá lórí yínyín Olórun fún ènì tí Ó jé àti ohun tí Ó máa mú wá wà sí ayé nípase Jésù. Àwon àngèlì, yàlni ẹ́nu ní ojú àwon ènìyàn,wón ní ìyàlẹ́nu nípa ìran tí Olórun. Àwon olùsó àgùntàn tí túbò gbódò ni ìdànílójú pé Olórun lo ye fún ìjosìn àti ìyìn wón tó ga jù lo.
Àdúrà: Bàbá, mi kò lè lóye bí ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ tí È jé. Láàárín Kérésìmesì yìí È mú mi darí àfiyèsí rẹ sórí bí ìjosìn mi se ye fún Yín. È máa jé kí n pàdánù àgbàyanu títóbi Yín láé. A sèdá gbogbo ohun ni òrun àti lórí ayé láti sìn Yín. kò séni tó sún mó bí È se jé ológo sí.
Gbà àwòrán tónìí jáde nibi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìtàn Kérésìmesì jẹ́ èyí tó ní ọlá jùlọ lóòótọ́: èyí tó dá lóríi ìṣòótọ́ Ọlọ́run, agbára, ìgbàlà, àti ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn. Jẹ́ kí a lọ lórí ìrìn àjò ọlọ́jọ́ mẹ́ẹ̀dọ́ńgbọ̀n láti ṣe àwárí ètò pípé Ọlọ́run láti gba ayé lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn ìlérí tí a mú wá sí ìmúṣẹ nípa ìbí Ọmọ Rẹ̀.
More