Saamu 55:16-17

Saamu 55:16-17 YCB

Ṣùgbọ́n èmi pe Ọlọ́run; OLúWA yóò sì gbà mí. Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sán èmi sọkún jáde nínú ìpọ́njú, o sì gbọ́ ohùn mi.